Wednesday, 18 September 2024

Atupa

Atupa (Weird but true!!.) A narration of weird but through stories in Yoruba Language.

ORUKO AWON ERANKO NI EDE YORUBA (Animals and Their Various names in Yoruba)

Cobra * Ọka

Ox , Bull * Malu
Spit-Snake *Ṣebe
Dog * Aja
Hedgehog *  Linli

Grasscutter - Oya

Pangolin * Akika
Crocodile * Ọoni
Alligator * Ahọnrihọn
Pig * Ẹlẹdẹ
Vulture * Igun, Gunnugun, Gurugu, Akala
Wood-Carrier * Arigiṣẹgi
Hawk * Asa
Palm-Bird * Ologiri
A species of Bird * Olofẹrẹ
Sparrow * Ologoṣẹ
Peacock * Ọkin
Squirrel * Ọkẹrẹ
Rabbit * Ehoro
crickets * Okinrin
Pouch Rat * Okete
Wild Goat * Edu
A species of Deer * Ekulu
Shark * Akurakuda
Rat/Mouse * Eku/Ekute
Earthworm * Ekolo
Sing Bird * Ẹyẹ-Orin
Partridge * Aparo
Horse * Ẹṣin
Donkey * Kẹtẹkẹtẹ
Camel * Rakunmi
Ass * Ibakasiẹ
Bat * Adan
Pelican * Ẹyẹ-Ofu
Water-bird * Osin
Dove * Adaba
Viper * Paramọlẹ
Sea-Gulls * Pẹju-pẹju
Yellow-haired Monkey * Sọmidọlọti/Oloyo
Sea-Bird * Yanja-yanja
Mosquito * Ẹfọn/Yanmu-yanmu
A species of Beetles * Yanrinbo
Raven * Ẹyẹ-Iwo
Snail * Igbin/Aginniṣọ
Freshwater Snail * Iṣawuru
Stay * Igala
Steer * Ẹgbọọrọ-Akọ Malu
Trout * Ẹja
Buffalo * Ẹfọn
Monkey * Ọbọ .
Ape * Ẹdun
Lizard * Alangba, -
Lobster * Alakasa
Boa * Constrictor Ere
Boar Ẹlẹdẹ * Igbo,
Gorilla, Baboon * Inaki, Inoki, Iro
Chimpanzee * Elegbede
Phython-Constrictor * Ojola
Electric Fish * Ojiji
Scorpion * Ojogan/Akeekee
Toad * Kọnkọ
Antelope * Egbin
Tick/Flee * Eegbọn
Hippopotamus * Erinmi
Rhinoceros * Ẹranko bi Imado.
Reynard (Fox) * Kọlọkọlọ
Hyena/Wolf * Ikoko
Giraffe * Agbanrere
Cow * Abo-Malu
Crab * Akan
Wild Pigeon * Oriri
Porcupine * Oorẹ, Eerẹ, Ojigbọn
Black-Ants * Tanpẹpẹ
Centipede * Tanisanko
Millipede * Ọkun
Goanna * Awonrinwon
Frog * Ọpọlọ
Chicken * Oromọ-Adiẹ
Nocturnal Animal * Ajao
Hound * Aja-Ọdẹ -
Elephant * Erin/Ajanaku
Sheep * Aguntan
Ram * Agbo
Woodcock * Agbe
A species of Woodcock * Aluko
White-feathered Bird * Lekeleke
Chamelon * Ọga, Alagẹmọ
Crane-Bird * Akọ -
Parrot * Odidẹrẹ
Ostrich * Ogongo
White-Ant * Ikan, Ikamudu
Tortoise * Ijapa
Tiger * Ẹkun
Lion * Kiniun
Pigeon * Ẹyẹle
Pig/Swine * Ẹlẹdẹ
Eagle * Idi .
Guinea Fowl * Awo
Guinea Fowl * Ẹtu
Guinea Pig * Ẹmọ-Ile
Jelly-Fish * Ẹja-Odo
A species of Bird * Afẹrẹgbojo/Afe-imojo
Spider * Alantakun
Butterfly * Labalaba
Bee * Oyin
Cockroach * Ayan
Cricket * Irẹ
Crab * Akan
Housefly * Eṣinṣin/Eṣin
Gnats * Kokoro-Ojuọti
Wall-Gecko Ọmọnle
Mouse * Eliri
Colt Young Horse * Agodongbo
Woodpecker * Akoko
Palm-Bird * Ẹga
Insect * Ipin
Red-Ant * Abonilejọpọn
Civet-cat * Ẹta
Zebra  *Egbin


Owl * Owiwi
Lice * Ina-Ori
Bed-bug * Idun
Leopard * Amọtẹkun
Hind * Abo-Agbọnrin
Cat * Ologinni
Turkey * Tolotolo
Swallow * Alapandẹdẹ
Kine * Abo-Malu
Stallion * Akọ-Ẹṣin
Gadfly * Iru, Eṣinṣin- N la
Duck * Pẹpẹyẹ
Jackal * Akata/Ajako

 

 

 

 

Credit link:  https://www.facebook.com/itanawonakoni/posts/oruko-awon-eranko-ni-ede-yorubaanimals-and-their-various-namecobra-%E1%BB%8Dkaox-bull-ma/714572542076334/

News Letter

Subscribe our Email News Letter to get Instant Update at anytime

About Oases News

OASES News is a News Agency with the central idea of diseminating credible, evidence-based, impeccable news and activities without stripping all technicalities involved in news reporting.